This is the Trace Id: f39a8e5900e68dade457879f8346a0b5
Fò sí àkóónú gangan Azure Copilot Windows Surface Xbox Outlook Accessories Microsoft AI Microsoft Security Azure Dynamics 365 Microsoft 365 for business Microsoft Power Platform Windows 365 Developer Center Documentation Microsoft Learn Microsoft Tech Community Microsoft Marketplace Visual Studio Marketplace Rewards View Sitemap

Internet Explorer 11 (32-bit) fún Windows 7 NÌKAN

Internet Explorer yóò dópin, a kí yóò sì ṣàtìlẹ́yìn fún-un mọ́ láti ọjọ́ 15, oṣù Kẹfa, ọdún 2022. Bí ojúlé wẹ́ẹ̀bù yòówù tí o bá lọ bá nílò Internet Explorer, o lè múu ṣàtúnkójọ pẹlú ipò IE nínú Microsoft Edge. Microsoft Edge ni aṣàwákiri tí Microsoft gbani níyànjú láti lò.

Pàtàkì! Yíyan èdè kan nísàlẹ̀ yìí yóò ṣàyípadà gbogbo àkóónú ojú-ìwé náà sí èdè yẹn.

Ìgbé-fáìlì-wálẹ̀
  • Ẹ̀yà:

    11.0.0.4

    Ọjọ́ Àtẹ̀jáde:

    15/2/2023

    Orúkọ Fáìlì:

    EIE11_YO-NG_MCM_WIN7.EXE

    Ìwọ̀n títóbi Fáìlì:

    32.1 MB

      Internet Explorer yóò dópin, a kí yóò sì ṣàtìlẹ́yìn fún-un mọ́ láti ọjọ́ 15, oṣù Kẹfa, ọdún 2022.
      Bí ojúlé wẹ́ẹ̀bù yòówù tí o bá lọ bá nílò Internet Explorer, o lè múu ṣàtúnkójọ pẹlú ipò IE nínú Microsoft Edge. Microsoft Edge ni aṣàwákiri tí Microsoft gbani níyànjú láti lò.
      Fún àlàyé síwájú síi, fún àwọn ìlé-iṣẹ́ tàbí aṣàkóso IT, nípa Internet Explorer 11, jọ̀wọ́ tẹ ibí.
  • Àwọn Ìlànà-iṣẹ́ Ẹ̀rọ tó ní Àtìlẹ́yìn

    Windows 7 Service Pack 1

    • Kọmputa/ Aṣètò ìgbésẹ̀: Kọmputa pẹ̀lú aṣètò ìgbésẹ̀ 233MHz tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ (A dámọ̀ràn aṣètò ìgbésẹ̀ Pentium)
    • Ààyè ìrántí: 512MB
    • Ààyè Awakọ̀ Ẹ̀yà Àfojúrí ti inú:70MB
    • Àfihàn: Super VGA (800 x 600) tàbí alabojuto rẹsoluṣọn tó ga pẹ̀lú àwọn àwọ̀ 256.
    • Àwọn ẹ̀yà tó ṣeé yọ kúrò: Módẹ̀mù tàbí àsopọ̀ Ayélujára; Máùsì Microsoft, Microsoft IntelliMouse, tàbí ẹ̀rọ àtọ́ka mìíràn tó báamu.
  • Láti fi Internet Explorer 11 sórí ẹ̀rọ, tẹ Gbàá láti ayélujára, kí o sì tẹ̀lé àwọn ìtọ́sọ́nà tí ó wà lórí ìbòjú rẹ̀.